Awọn Iroyin ati Ero
Àwọn Ìròyìn Àgbáyé Mùsùlùmí àti Àárín Gbùngbùn Ìlà Oòrùn

Pada si "Àwọn Ìròyìn Àgbáyé Mùsùlùmí àti Àárín Gbùngbùn Ìlà Oòrùn"

Àwọn Ìròyìn Àgbáyé Mùsùlùmí àti Àárín Gbùngbùn Ìlà Oòrùn
Folashade
Awọn ifiweranṣẹ: 1
Ẹ darapọ̀: Wed Oṣu kejila 10, 2025 10:09 pm
Olubasọrọ:

     Folashade Awọn ifiweranṣẹ: 1    Ẹ darapọ̀: Wed Oṣu kejila 10, 2025 10:09 pm    Olubasọrọ:   


Firanṣẹ nipasẹ Folashade »

Esin030 Ẹ gbọ́! Tani Habib Dẹ̀dẹ̀wùrẹ̀ Agége ti nwon pe ni Zindiq lori Ayelujara EsinIslam

Dẹ̀dẹ̀wùrẹ̀ Agége, Zindiq ati beebe lo ni awon apele ti awon osise tabi awon olulo lori ayelujara EsinIslam fun Habib Abdullahi ni Agege ti i se ikan ninu awon omo alufa agba ni Ile Yoruba ti opolopo ri gege bi oludojuti ati amunibuni eran ibiye ti o n fi orisirisi awon ede-aiyede ati ifenu da Esin Islam loju ru ni orile ede Naijiriya. E wo fanran fidio yii:

https://www.esinislam.com/YorubaZindiqVideosTV-c

Mo ri fanran fidio yi lori ayelujara EsinIslam ti o se alaiye awuyewuye lori iwuwa ati modaru Esin Habib Agege yi ni igba akoko lose ti o k'oja. Mo wo gbogbo awon ikan fidio naa patapata. Lehin eyi ni mo wa kan si awon baba-baba wa ti nwon je agba alufa paapaa julo ni Ilorin. Oro po ninu iwe kobo ni alaiye ti nwon se fun mi l'ori oro alufa Habib yii.

Sugbon ki n to lee menu baa oun gbogbo ti mo gbo nipa okunrin ti opolopo mo si Mudeer Al-Markaz yii, yio dara ki n se eda ona ti awon osise tabi awon olulo lori EsinIslam se alaiye eniti o n je Zindiq ninu Esin. E maa bami kalo...!

Ni akoko eyi ni bi nwon ti se ko akole afanran onifidio naa:

Habib Dedewure Lagege Is A Yoruba Zindiq* حبيب دَيْدَيْوُورَي من أغيغي هو زنديق* يوروبا

Ede Oyinbo ati Ede Larubawa nikan ni mo ri l'ori afanra yii ti nwon ti se alaiye eniti o n je Zindiq ati Dedewure latari eebu ti Habib n bu awon Sahabah (r.a.) ti o si n bu enu ete kan awon onimimo ti isaaju bi Imam Al-Bkhari ati beebe lo. Fun anfani awon ti nwon ko le be afanran yi wo, ma gbiyanju lati se itumo Ede Oyinbo naa si Ede Yoruba ni tikalara ti emi.

Eyi ni alaiye eniti o n je Zindiq ninu Esin Islam gege bi nwon ti se akosile re ni Ede Oyinbo:

*Zindiq in Islam, a zindiq is defined as someone who outwardly professes Islam but conceals disbelief and heresy, more severe than a hypocrite i.e. someone who outwardly acknowledges prophethood but in his heart maintains positions that oppose Islamic law or hold destructive opinions as hemiplegic ignorant Habib Dedewure of Agege does.
( copied from the page https://www.esinislam.com/YorubaZindiqVideosTV-c )

Alaiye eniti o n je Zindiq ninu Esin Islam gege bi nwon ti se akosile re ni Ede Larubawa:

الزنديق* في الإسلام هو من يظهر الإسلام ظاهريًا ولكنه يخفي الكفر والبدع، وهو أشد من المنافق أي من يقرّ بالنبوة ظاهريًّا ولكنه في قلبه يحتفظ بمواقف تعارض الشريعة الإسلامية أو يحمل آراء هدامة كما يفعل الجاهل المشلول حبيب دَيْدَيْوُورَي من أغيغي.
( copied from the page https://www.esinislam.com/YorubaZindiqVideosTV-c )

Ni ti temi, eyi ni bi emi ti gbo alaiye yi ye ni Ede Yoruba:

*Nínú ẹ̀sìn Islam, a túmọ̀ zindiq gẹ́gẹ́ bí ẹni tí ó ń jẹ́wọ́ ẹ̀sìn Islam ní òde ara rẹ̀ ṣùgbọ́n tí ó ń fi àìnígbàgbọ́ àti àìgbàgbọ́ bo ara rẹ̀ mọ́lẹ̀, tí ó le ju Munafiq alágàbàgebè lọ, ìyẹn ni ẹnìkan tí ó ń jẹ́wọ́ jíjẹ́ Ojise Anabi (Muhammad) ní òde ara rẹ̀ ṣùgbọ́n tí ó ń di àwọn ipò tí ó lòdì sí òfin Islam mú tàbí tí ó ní àwọn èrò ìparun (si ẹ̀sìn Islam) gẹ́gẹ́ bí Habib Dedewure, amúkún òpè ènìyàn Agege, ṣe ń ṣe.
( translated as understood by myself )

Yio wumi lati menu ba dire ninu oun ti awon agbalagba alufa paapa julo ni Ilorin wi fun mi lori oro Habib yii ninu awon ti nwon ba baba re l'ogba. Sugbon ki n to le bere eleyii, yio wumi ki oluka ifiranse yii ba wa dasi oro yii latari ijiroro ni oju ewe yii. Enikeni lee ba wa dasi oro yii, paapaa julo pelu imo ati oye. Imo ni o ni Adini, e jowo ogbon ori ko. Ti enikeni ba si fe bawa dasi ijiroro yii, ki a ma bu awon olulo egbe wa lori aiyelujara yii tabi ki a so oro odi si awon osise EsinIslam ti nwon n fun wa ni anfaani ijiroro yii.

Eyin omo Yoruba, eyin Omo Kaaro-O-Jiire, Omoluabi ti o fi dori awa omo Ilorin e je ki a dasi oro yii pelu imo ati oye ti o peye...!

E se!!

Folashade (Sis.)

Fi èsì kan ranṣẹ

Ẹ gbọ́! Tani Habib Dẹ̀dẹ̀wùrẹ̀ Agége ti nwon pe ni Zindiq lori Ayelujara EsinIslam



Fún Ìdáhùn

Pada si "Àwọn Ìròyìn Àgbáyé Mùsùlùmí àti Àárín Gbùngbùn Ìlà Oòrùn"

Rashid
Awọn ifiweranṣẹ: 2
Ẹ darapọ̀: Wed Oṣu kejila 10, 2025 10:19 pm
Olubasọrọ:

     Rashid Awọn ifiweranṣẹ: 2    Ẹ darapọ̀: Wed Oṣu kejila 10, 2025 10:19 pm    Olubasọrọ:   


Firanṣẹ nipasẹ Rashid »

Iru eru wo ni eyi? Bawo ni eniti o ko akosile yi se lero wipe ko ni si eniti yio mo ete oun?

Ti iwo gan an naa ba fe bu Sheikh Habib Baba L'Agege gege bi obirin bi re Iya Gbonka ni Ibadan se n se, ki o kuku jade sita ki o se bee. Ma se go si eyin ika kan lori ayelujara yii rara. Abosi nla gbaa ni eyi je.

O pe ara re ni omo Ilorin. Se iwa omo oko Ilorin ni ki o maa kun awon ti nwon n soko oro buruku si orule ile re? Awon agbalagba alufa oloriburuku wo ni nwon soro fun o lati Ilorin ti o wa wa sibi yii lati maa tan wa je. Awa omo egbe Ogo Ilorin ti n gbe igbese lati koko tu asiri eyin alabosi omo Ilu wa ki a si fi oju elesin nyin sita.

O so wipe nitori ijiroro lori imo ati oye ni o fi ko akosile re radarada yii. O si so siwaju wipe o ko fe ki enikeni bu eniyan tabi ta abuku ninu ijiroro re. Alabosi ni iwo gan an. Se oro re gbogbo yi ki i se ebu? Se eyin ni gbogbo oun ti o so nipa Mudeer Markaz nibi? Se eyin tabi aponle Ilu Ilorin ni o se sibi? Otofasoke yido bori, bi eniyan ko ri o, Olohun n ri o, iwo Ferushade ti o pe ara re ni Folashade yii.

Mo mo wipe comment mi yii ko ni pe ti awon eniyan nyin ni EsinIslam yio fi pare. Sugbon emi ti so temi. Beeni mo ti se ojuse gege bi ikan ninu awon Ogo Ilorin ti e n binu.

وَمَكَرُوا وَمَكَرَ اللَّهُ ۖ وَاللَّهُ خَيْرُ الْمَاكِرِينَ

Fi èsì kan ranṣẹ

Re: Ẹ gbọ́! Tani Habib Dẹ̀dẹ̀wùrẹ̀ Agége ti nwon pe ni Zindiq lori Ayelujara EsinIslam



Fún Ìdáhùn

Pada si "Àwọn Ìròyìn Àgbáyé Mùsùlùmí àti Àárín Gbùngbùn Ìlà Oòrùn"

PrincessAdeola
Awọn ifiweranṣẹ: 1
Ẹ darapọ̀: Wed Oṣu kejila 10, 2025 10:34 pm
Olubasọrọ:

     PrincessAdeola Awọn ifiweranṣẹ: 1    Ẹ darapọ̀: Wed Oṣu kejila 10, 2025 10:34 pm    Olubasọrọ:   


Firanṣẹ nipasẹ PrincessAdeola »

Imoran fun Atunse (Advice for Correction)

Assalamu alaikum everyone,

Ustaz Rashid, kin legbe, kin le ju? Oro yii abi omiran? E wo ni ogun epe? Kini sister wa Folashade ti i so ti o fi di ti pipe nwon di alabosi on this issue, ehn? N je e tire fi ara bale lati ka oun ki nwon ko at all?

Abi ki eyin odidi alufa maa soro odi pe awon agbalagba alufa ni Ilorin or any where else for that matter ni oloriburuku. Haba!

Ustaz Rashid, eyi ti e ko yin nipa Sister Shade ku dire kaato. E ya tete lo delete re kiakia o.... Eyin gan an ni e fa ti anybody ba fi esun "bullying" kon nyin lori oro nyin yii. Haha, o po. Eyi poju. E ya tete se atunse lori post nyin yii ki e si delete post naa. Eleyi is too much, brother wa.

Emi ko ni ti i menu ba awon issues miran ti mo se akiyesi re ninu post nyin yii except ti e ba refuse lati se atunse tabi continue lori asoju yii.

Adeola

Fi èsì kan ranṣẹ

Re: Ẹ gbọ́! Tani Habib Dẹ̀dẹ̀wùrẹ̀ Agége ti nwon pe ni Zindiq lori Ayelujara EsinIslam



Fún Ìdáhùn

Pada si "Àwọn Ìròyìn Àgbáyé Mùsùlùmí àti Àárín Gbùngbùn Ìlà Oòrùn"

Adeshina
Awọn ifiweranṣẹ: 1
Ẹ darapọ̀: Wed Oṣu kejila 10, 2025 10:30 pm
Olubasọrọ:

     Adeshina Awọn ifiweranṣẹ: 1    Ẹ darapọ̀: Wed Oṣu kejila 10, 2025 10:30 pm    Olubasọrọ:   


Firanṣẹ nipasẹ Adeshina »

Esin007 Habib ni Dẹ̀dẹ̀wùrẹ̀ Agége, Zindiq ilẹ̀ Yorùbá ẹ̀yín Ológógóró Ilorin Ẹlẹ́gbẹ́ Awo Ẹgbẹ́ Aragberi si ni ọmọ àlè Yorùbá

Rashid tàbí kí ni o pè ara rẹ, gbọ́! Ẹ̀yin akẹ́kọ̀ọ́ Dẹ̀dẹ̀rù Agége, Zindiq àti àwọn ọmọ àlè Ilorin Mesujamba tí wọ́n ń pe ara wọn ní Ogo Ilorin yẹ kí a lé nyín kúrò ní ilẹ̀ Yorùbá patapata. Ayé ti lajú pọ̀ ju àwọn ọgbọ́n Jalabi yín lọ báyìí, ayé si ti lajú pọ̀ ju àwọn ète nyín ní orúkọ ìmọ̀ ẹ̀sìn Islam tí ẹ kò tíì mọ̀ rárá.

Àní ìwọ pàápàá, Rashid ní ìgboyà láti máa bully àwọn obìnrin tó ní ìmọ̀ dáadáa sàn ju ìwọ lọ níbí.

Ó ti hàn gbangba báyìí pé gbogbo yín, Ológógórì Ilorin yìí jẹ́ ọ̀tá ẹ̀sìn Islam. Gbogbo yín ni ojú yóò tì, a ó sì fi òfin lé yín lọ́wọ́ láìpẹ́. Gbogbo yín ni Dẹ̀dẹ̀wùrẹ̀ àti gbogbo àwọn àlùfáà èṣù tí ibi ibi yín dá sílẹ̀. Tí ẹ kò bá fẹ́ràn wípé Habib Mudirru ni Dẹ̀dẹ̀wùrẹ̀ àti Zindiq ló ń fa ìṣòro ní ilẹ̀ Yorùbá gẹ́gẹ́ bí EsinIslam.Com ṣe tẹ̀ ẹ́ jáde, ẹ lọ wa mọ́ babwire kí gbogboo nyín sánkú dànù kí a lè ní àlàáfíà ní ilẹ̀ Yorùbá.

Gbogbo yin kò ní àǹfààní kankan fún gbogbo ènìyàn ní orílẹ̀-èdè yìí àyàfi pé kí ẹ rẹ́ wọn jẹ pẹ̀lú kíkà Yasin irọ́ tí kò wúlò. Gbogbo ẹ̀yín àwọn wèrè wọ̀nyí.

R A Adeshina

Fi èsì kan ranṣẹ

Re: Ẹ gbọ́! Tani Habib Dẹ̀dẹ̀wùrẹ̀ Agége ti nwon pe ni Zindiq lori Ayelujara EsinIslam



Fún Ìdáhùn

Pada si "Àwọn Ìròyìn Àgbáyé Mùsùlùmí àti Àárín Gbùngbùn Ìlà Oòrùn"

Rashid
Awọn ifiweranṣẹ: 2
Ẹ darapọ̀: Wed Oṣu kejila 10, 2025 10:19 pm
Olubasọrọ:

     Rashid Awọn ifiweranṣẹ: 2    Ẹ darapọ̀: Wed Oṣu kejila 10, 2025 10:19 pm    Olubasọrọ:   


Firanṣẹ nipasẹ Rashid »

Mi ko fe fesin mo rara lori oro yii. Sugbon ti nwon ba bu e ti o ko soro, nwon a lero wipe eru ija lo n ba e. Bakanaa ti a ba ko ti a ni a ko ni se oogun ika mo, eyin eniburuku ti e o je iwo yii, ko ni je!

Gbogbo eyin ti e n soro buruku ranse si mi ati si gbogbo Ogo Ilorin, se eyin naa ko ri wipe eyin gan an ni alabosi. Eni Sunnah ti o peye ni emi tikalara mi n se - Alhamu lillahi (ope ni fun Olohun). Eyin paapa ni alabuku eda - akewu moka eto, eyin akewu-kete gbogbo.

E mi naa ti so lai mo'ye igba wipe, asise nla gbaa ni bi Mudirul Markaz Sheikh Habibullah ti n so oro si awon Sahaba ati awon Imams nla ninu Islam bi Imam Bukhari ati beebe lo. Sugbon emi ko fi owo si ki enikeni maa bu awon agbalagba wa ni Ilu Ilorin gege bii Sheikh Adam Al-Ilori, Sheikh Kamal-ud-deen Al-Adabi tabi baba wa Oba Ilorin (Sheu Allahu yasmuka mina nas).

Ki i se ise mi ni lati se agbenuso fun enikeni tabi fun egbe kankan bi ko se lati se deede ki n si duro lori otito nidiwon bi o se ye mi mo. Nigbati emi naa mo opolopo ninu awon omo Markaz ati awon omo Adabiyah ti nwon n pe Mudirul Markaz ni Dedewure, oba-aro ati beebe lo, bawo ni ti eyin Salafi 1990 EsinIslam yio se wa jo mi l'oju? Beeni ko si enikeni ti o ran nyin nise aburu nyin yii. Ti ara nyin ati ti imo akatakiti nyin ti e mo ni e nse.

Mo gbo wipe Sheikh wa, Dr. Abu-Abdullah Adelabu funra nwon ba awon baba-baba wa ni Ilorin soro lori awon awuyewuye ti o n waye yii. Mo gbo lati odo ikan pataki ninu awon Ogo-Ilorin ti nwon wa ni United Kingdom wipe awon baba wa bi baba agba Justice Harun, the Grand Qadi of Kwara State se abewo sii awon Sheikh Dr. Adelabu ni London ni ose bi melo sehin ti nwon si so opo oro laiko si ija tabi wahala lori oro yii.

Ki lo fa a ti awa omo nwon ati awa akeko nwon yi o maa bu ara wa lori oro yii? Kin lo le fa ija ajadiju? E jowo eyin onijadijagan, e ma se see akoba fun Dr. Adelabu lori oro yi o. Emi naa paapa mu omi imo ati opolopo oore lati odo Sheikh wa Sheikh Dr. Abu-Abdullah Adelab. Beeni mo mo Sheikh wa yi siwaju gbogbo eyin modaru yii.

Gbogbo eniti ti o so mi lenu tabi ti o soro odi simi lori oro yii, gbogbo nwon patapata ni mo fa le Olohun l'owo ki O se idajo nwon. Ki Olohun si i fi oju asebi han lara gbogbo eyin aritenimoowi afi apaadi dudu bo ti e mole...

E beru Olohun!

آمَنَ الرَّسُولُ بِمَا أُنزِلَ إِلَيْهِ مِن رَّبِّهِ وَالْمُؤْمِنُونَ ۚ كُلٌّ آمَنَ بِاللهِ وَمَلَائِكَتِهِ وَكُتُبِهِ وَرُسُلِهِ لَا نُفَرِّقُ بَيْنَ أَحَدٍ مِّن رُّسُلِهِ ۚ وَقَالُوا سَمِعْنَا وَأَطَعْنَا ۖ غُفْرَانَكَ رَبَّنَا وَإِلَيْكَ الْمَصِيرُ

لَا يُكَلِّفُ اللهُ نَفْسًا إِلَّا وُسْعَهَا ۚ لَهَا مَا كَسَبَتْ وَعَلَيْهَا مَا اكْتَسَبَتْ ۗ رَبَّنَا لَا تُؤَاخِذْنَا إِن نَّسِينَا أَوْ أَخْطَأْنَا ۚ رَبَّنَا وَلَا تَحْمِلْ عَلَيْنَا إِصْرًا كَمَا حَمَلْتَهُ عَلَى الَّذِينَ مِن قَبْلِنَا ۚ رَبَّنَا وَلَا تُحَمِّلْنَا مَا لَا طَاقَةَ لَنَا بِهِ ۖ وَاعْفُ عَنَّا وَاغْفِرْ لَنَا وَارْحَمْنَا ۚ أَنتَ مَوْلَانَا فَانصُرْنَا عَلَى الْقَوْمِ الْكَافِرِينَ

Rashid

Fi èsì kan ranṣẹ

Re: Ẹ gbọ́! Tani Habib Dẹ̀dẹ̀wùrẹ̀ Agége ti nwon pe ni Zindiq lori Ayelujara EsinIslam



Fún Ìdáhùn

Pada si "Àwọn Ìròyìn Àgbáyé Mùsùlùmí àti Àárín Gbùngbùn Ìlà Oòrùn"

Iyabo2
Awọn ifiweranṣẹ: 2
Ẹ darapọ̀: Wed Oṣu kejila 10, 2025 10:14 pm
Olubasọrọ:

     Iyabo2 Awọn ifiweranṣẹ: 2    Ẹ darapọ̀: Wed Oṣu kejila 10, 2025 10:14 pm    Olubasọrọ:   


Firanṣẹ nipasẹ Iyabo2 »

Habib Baba Eko ni Dedewure Oooo. A se ko gbo Larubawa. Oju ti olodo ti o fe so ara re di olori awon oni mimo ni Ile Yoruba.

Bawo ni Habib Olodo ti ko le soro ni Larubawa bi even awon aburo mi okunrin ati obirin se ni effrontery lati soro nipa Imam Al-Bukari (Rahimahu Allahu).

Ko si eniti yio se itabuku awon eni Olohun bi Imam Al-Bukhari ti atubotan re yio dara. Oro idoju Larubawa Habib iseju meta yii je ki n tun ni iberu Olohun si ni. A se lati aiye lo ni abuku Habib yio ti bere... Allahu Akbar... Mo se Titobi Olohun...Oooo

Fi èsì kan ranṣẹ

Re: Ẹ gbọ́! Tani Habib Dẹ̀dẹ̀wùrẹ̀ Agége ti nwon pe ni Zindiq lori Ayelujara EsinIslam



Fún Ìdáhùn

Pada si "Àwọn Ìròyìn Àgbáyé Mùsùlùmí àti Àárín Gbùngbùn Ìlà Oòrùn"

Fún Ìdáhùn